Mofi tòwòtòwò te àtè jísé yìí sí àwon òsìsé ilé isé BÓND-F.M fún ìrànplówó láti gbàmí sí àyè isé èdè YORÙBÁ tí ó bá sí sílè fún síse, gégé bí mo tise àwárí araà mi pé mo dángájíá nínú èdè mi àyàmí mi tí n se YORÙBÁ, àti láti mò síwájú si nínú YORÙBÁ àti èdè nâ kí gbogbo àgbáyé lé mò wípé kìí se egbé èdè òyìnbó tí amò sí "gèésì". Ó wùmí láti sisé sin orílè èdè mi NÌGÉRÍÀ nítorípé moní ìfé rè dé góngó èmí mi pàápàá jùlo ìran àti èbùn tèmi tín se YORÙBÁ, ejòwó erànmílówó kò sí olùrànlówó kankan fún mi láti kàwé, òdómodé kùrin sì ni mí, eràmílówó fún isé, mi ò fé di omokómo nípasè pé kò sí olùrànlówó, mi òsì fé kí oun ayé fejú mó mi ju báàyí lo. Kí OLÓRUN rà wá lówó. Ààmín.
Comments
RSS feed for comments to this post.